Jump to content

Tatum O'Neal

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Tatum O'Neal
Tatum O'Neal - November 2014
Ọjọ́ìbíTatum Beatrice O'Neal
5 Oṣù Kọkànlá 1963 (1963-11-05) (ọmọ ọdún 61)
Los Angeles, California, U.S.
Iṣẹ́Actress, author
Ìgbà iṣẹ́1973–present
Olólùfẹ́
John McEnroe
(m. 1986; div. 1994)
Àwọn ọmọ3
Parent(s)Ryan O'Neal
Joanna Moore
Àwọn olùbátanGriffin O'Neal (brother)
Patrick O'Neal (sportscaster)


Tatum O'Neal jẹ olukọwe ati óṣere lobinrin ilẹ America ti a bini ọjọ karun óṣu November ni ọdun 1963[1].

Igbesi Ayè Arabinrin naa

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Tatum ni wọn bisi Los Angeles, California fun óṣèrè Ryan O'Neal ati Joanna Moore. Awọn obi óṣere lobinrin naa pinya ni ọdun 1967[2][3]. Iya Tatum ku ni ọmọọdun mẹta lelọgọta lori arun jẹjẹrẹ ti lungs.Ni ọdun 2021, O'Neal kopa ninu filmu "Maṣè gbagbe" to dalori idani lẹ̀kọ ati iko ówó jọ lati ja fun aisan Alzheimer[4].

ọdun Akọle Ipa ti óṣèrè lobinrin naa ko Akiyesi
1973 Paper Moon Addie Loggins David di Donatello Award for Best Foreign Actress (tied with Barbra Streisand for The Way We Were)
Golden Globe Award for New Star Of The Year – Actress
Nominated – Golden Globe Award for Best Actress – Motion Picture Musical or Comedy
1976 The Bad News Bears Amanda Wurlitzer
Nickelodeon Alice Forsyte
1978 International Velvet Sarah Brown
1980 Circle of Two Sarah Norton
Little Darlings Ferris Whitney
1982 Prisoners Christie Unreleased
1985 Certain Fury Scarlet
1992 Little Noises Stella
1996 Basquiat Cynthia Kruger
2002 The Scoundrel's Wife Camille Picou San Diego Film Festival Award for Best Actress
2003 The Technical Writer Slim
2006 My Brother Erica
2008 Saving Grace B. Jones Grace B. Jones
2010 The Runaways Marie Harmon
Last Will Hayden Emery
2012 This Is 40 Realtor Cameo
2013 Mr. Sophistication Kim Waters
2015 Sweet Lorraine Lorraine Bebee
She's Funny That Way Waitress Cameo
2017 Rock Paper Dead Dr. Evelyn Bauer
2018 God's Not Dead: A Light in Darkness Barbara Solomon
2019 The Assent Dr. Hawkins
2021 Not to Forget Doctor
Ọdun Akọle Ipa ti óṣere obinrin naa ko Akiyesi
1984 Faerie Tale Theatre Goldilocks Goldilocks and the Three Bears"
1989 CBS Schoolbreak Special Kim Episode: "15 and Getting Straight"
1993 Woman on the Run: The Lawrencia Bembenek Story Laurie Bembenek TV movie
2003 Sex and the City Kyra Episode: "A Woman's Right to Shoes"
2004 8 Simple Rules Ms. McKenna Episode: "Opposites Attract: Part 3: Night of the Locust"
Law & Order: Criminal Intent Kelly Garnett Semi-Detached"
2005 Ultimate Film Fanatic Judge
2005–2011 Rescue Me Maggie Recurring role (Seasons 2–3, 5–7), Main role (Season 4); 39 episodes
2006 Dancing with the Stars Herself 5 episodes
Wicked Wicked Games Blythe Hunter 51 episodes
2008 Fab Five: The Texas Cheerleader Scandal Lorene Tippit TV movie
2010 RuPaul's Drag Race Herself Episode: "The Diva Awards"
2011 Ryan and Tatum: The O'Neals Herself
2015 Hell's Kitchen Herself Episode: "6 Chefs Compete"
2017 Criminal Minds Miranda White Episode: "Assistance Is Futile"
2018 Runaway Romance Veronica Adson TV movie

Ami Ẹyẹ ati Idanilọla

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Tatum jẹ ọdọ to kere julọ lati pegede ninu idije Ami ẹyẹ Akademi ni ọmọ ọdun mẹwa nibi ti ó ti ṣèrè gẹgẹbi Addie Loggins ninu èrè Paper Moon ni ọdun 1973[5]. Ni ọdun 1974,Tatum gba ami ẹyẹ Akademi gẹgẹbi oluranilọwọ óṣèrè lobinrin to dara ju[6].