Huang Xianfan
Ìrísí
Huang Xianfan | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Gan Jinying(甘錦英/甘锦英) Oṣù Kọkànlá 13, 1899 Fusui, Ṣáínà |
Aláìsí | January 18, 1982 Guilin, Ṣáínà | (ọmọ ọdún 82)
Cause of death | Stroke patients |
Resting place | Guangxi Zhuang Autonomous Region martyrs cemetery,the names of the martyrs cemetery inscribed by Deng Xiaoping(广西壮族自治区烈士陵园,园名由邓小平亲笔题写) |
Orílẹ̀-èdè | Orílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ Ṣáínà |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Orílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ Ṣáínà |
Ẹ̀kọ́ | Normal Unifasiti ni Beijing(1926-1935), Unifasiti Tokyo(1935-1937) |
Iṣẹ́ | Representatives of the National People's Congress(NPC), Members of the CPPCC National Committee |
Ìgbà iṣẹ́ | 1954-1958, 1980-1982 |
Gbajúmọ̀ fún | As the father of Zhuang studies(壮学之父), the School's leader of Bagui(八桂学派领袖) and Wu Nu(无奴学派导师) |
Ọmọ ìlú | Qusi village, Qujiu town, Fusui county |
Political party | Chinese Peasants' and Workers' Democratic Party |
Olólùfẹ́ | Liu Lihua(劉麗華/刘丽华) |
Àwọn ọmọ | Gan Jinshan(甘金山), Gan Wenhao(甘文豪),Gan Wenjie(甘文杰) |
Parent(s) | Gan Xinchang(甘新昌) |
Website | [3] |
Notes | |
Huang Xianfan (13 Oṣù Kọkànlá 1899 - 18 Oṣù Kínní 1982) je ojogbon (Professor) ìtàn omo ile Ṣáínà.
Igbesiaye
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wón bí Huang Xianfan ní ìlú Fusui, ìpínlè Guangxi ní ọdun 1899. Huang ló ilé èkó primary and junior secondary ni Qujiu àti Fusui, àti ni Nanning' High School ni Guangxi. Lèyìn rè ó ló sí Normal Yunifasiti ni Beijing (Beijing ni oluilu orile-ede Orílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ Ṣáínà) ni 1926-1935 àti Yunifasiti Tokyo (Tokyo ni oluilu orile-ede Japan) ni Japan ni 1935-1937. Leyin eyi ni o lo di ojogbon ìtàn ni Yunifasiti Guangxi ni Ṣáínà ni 1940-1982. [1]
Ìwé tó kọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- «Outline of Chinese History».Beiping Culture Society, 1932-1934
- «Brief Introduction on Tang Dynasty». The Commercial Press,1936
- «Save Nation Movement of Tai-Xue students in Song Dynasty».The Commercial Press,1936
- «Brief History of Zhuang nationality».Guangxi Peoples’s Press, 1957
- «No Slave Society in Chinese History». Guangxi Normal University Press ,1981
- «Nong Zhi Gao». Guangxi Peoples’s Press,1983
- «General History of Zhuang Nationality». Guangxi National Press ,1988
- «the Introduction on Chinese Ancient Books». Guangxi Normal University Press ,2004[2]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ www.china.com.cn:2008-12-08 [1]
- ↑ ma.www.china.com.cn:2009-07-17 [2] Archived 2009-11-01 at the Wayback Machine.
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: 黄现璠 |