Gao
Ìrísí
| ||||||||||||||||||
Gao je ilu kan ni orile-ede Mali bakanna o tun je oluilu fun Agbegbe Gao ni eba Odo Oya, iye awon eniyan ibe je 57,978 ni 2005.[1] Bakanna ohun tun ni oluilu ibi ayika ayika Gao.
Itan
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Lati igba to ti je didasile, Gao je gbongan fun idunadura ati ikeko, bakanna o tun je oluilu fun Ile Obaluaye Songhai. O ri bi okanna, ati asa kanna mo awon ilu idunadura Kakiri-Sahara ni Timbuktu ati Djenne.
Coordinates: 16°16′N 0°03′W / 16.267°N 0.050°W
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |